Niger Delta swamp forests

Àwòrán odò kan ní Delta

Niger Delta swamp forests (èdè Yorùbá: igbó irẹ̀ Niger delta) jẹ́ igbó erẹ̀ kan ní apa gúúsù orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó jẹ́ àwọn igbo irẹ̀ nínú omi tí ó mọ́ kongá ní Niger Delta ti odò Niger. Òun ni igbó irà tí ó tóbi jùlọ ní Áfríkà lẹ́yìn igbó irà Congo.[1][2][3][4] Bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé àwọn ìlú wà ní agbègbè igbó náà, àwọn ènìyàn kò gbé ní ibi ẹ̀ nítorí ó ṣòro láti kó ilé tàbí ọ̀nà kọjá irà náà, ṣùgbọ́n , èyí kò rí bẹ́ẹ̀ mọ́ nítori pé àwọn ilé isé epo ti ń wa kùsà epo ní ilẹ̀ irà náà.

  1. "Niger Delta swamp forests" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). World Wildlife Federation. Retrieved June 20, 2020. 
  2. "Map of Ecoregions 2017" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Resolve, using WWF data. Retrieved June 20, 2021. 
  3. "Niger Delta swamp forests" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Digital Observatory for Protected Areas. Retrieved June 20, 2021. 
  4. "Niger Delta swamp forests" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). The Encyclopedia of Earth. Retrieved June 20, 2021. 

From Wikipedia, the free encyclopedia · View on Wikipedia

Developed by Tubidy